Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dó, ekini tì ekeji ni ijọ meje. O si ṣe, li ọjọ keje, nwọn padegun, awọn ọmọ Israeli si pa ọkẹ marun ẹlẹsẹ̀ ninu awọn ara Siria li ọjọ kan.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:19-32