Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iranṣẹ ọba Siria si wi fun u pe, ọlọrun wọn, ọlọrun oke ni; nitorina ni nwọn ṣe li agbara jù wa lọ; ṣugbọn jẹ ki a ba wọn jà ni pẹtẹlẹ, awa o si li agbara jù wọn lọ nitõtọ.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:22-27