Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o kà awọn ipẹrẹ̀ awọn ijoye igberiko, nwọn si jẹ igba o le mejilelọgbọn: lẹhin wọn li o si kà gbogbo awọn enia, ani gbogbo awọn ọmọ Israeli jẹ ẹdẹgbarin.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:10-22