Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Benhadadi gbọ́ ọ̀rọ yi, bi o ti nmuti, on ati awọn ọba ninu agọ, li o sọ fun awọn iranṣẹ rẹ̀ pe, Ẹ tẹ́gun si ilu na.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:8-21