Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣimei si wi fun ọba pe, Ọrọ na dara, gẹgẹ bi oluwa mi ọba ti wi, bẹ̃ gẹgẹ ni iranṣẹ rẹ yio ṣe. Ṣimei si gbe Jerusalemu li ọjọ pupọ.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:30-40