Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ̀jẹ wọn yio si pada sori Joabu, ati sori iru-ọmọ rẹ̀ lailai: ṣugbọn si Dafidi ati si iru-ọmọ rẹ̀, ati si ile rẹ̀, ati si itẹ́ rẹ̀, alafia yio wà lati ọdọ Oluwa wá,

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:31-41