Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si wi fun u pe, Ṣe gẹgẹ bi o ti wi ki o si kọlù u, ki o si sin i, ki iwọ ki o le mu ẹ̀jẹ alaiṣẹ̀ kuro lọdọ mi ati kuro lọdọ ile baba mi, ti Joabu ti ta silẹ.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:27-34