Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ihin si de ọdọ Joabu: nitori Joabu ti tọ̀ Adonijah lẹhin, ṣugbọn kò tọ̀ Absalomu lẹhin: Joabu si sá sinu agọ Oluwa, o si di iwo pẹpẹ mu.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:22-30