Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 19:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si de ibẹ̀, si ibi ihò okuta, o si wọ̀ sibẹ, si kiyesi i, ọ̀rọ Oluwa tọ̀ ọ wá, o si wi fun u pe, Kini iwọ nṣe nihinyi, Elijah?

1. A. Ọba 19

1. A. Ọba 19:1-17