Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 18:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Obadiah si wà li ọ̀na, kiyesi i, Elijah pade rẹ̀: nigbati o mọ̀ ọ, o si doju rẹ̀ bolẹ, o si wipe, Ṣé iwọ oluwa mi Elijah nìyí?

1. A. Ọba 18

1. A. Ọba 18:3-10