Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 18:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elijah si wi fun awọn enia na pe, Emi, ani emi nikanṣoṣo li o kù ni woli Oluwa; ṣugbọn awọn woli Baali ãdọta-lenirinwo ọkunrin,

1. A. Ọba 18

1. A. Ọba 18:15-29