Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 18:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, ranṣẹ nisisiyi, ki o si kó gbogbo Israeli jọ sọdọ mi si oke Karmeli ati awọn woli Baali ãdọtalenirinwo, ati awọn woli ere-oriṣa irinwo, ti njẹun ni tabili Jesebeli.

1. A. Ọba 18

1. A. Ọba 18:11-29