Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 18:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, lẹhin ọjọ pupọ, ọ̀rọ Oluwa tọ Elijah wá lọdun kẹta, wipe, Lọ, fi ara rẹ hàn Ahabu; emi o si rọ̀ òjo sori ilẹ.

1. A. Ọba 18

1. A. Ọba 18:1-11