Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu si ṣe ere oriṣa kan; Ahabu si ṣe jù gbogbo awọn ọba Israeli lọ, ti o wà ṣaju rẹ̀, lati mu ki Oluwa Ọlọrun Israeli binu.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:25-34