Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu, ọmọ Omri, si ṣe buburu li oju Oluwa jù gbogbo awọn ti o wà ṣaju rẹ̀ lọ.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:27-34