Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti o rìn ni gbogbo ọ̀na Jeroboamu, ọmọ Nebati, ati ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀, eyiti o mu Israeli ṣẹ̀, lati fi ohun-asán wọn wọnni mu Oluwa, Ọlọrun Israeli binu.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:25-34