Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀ wọnni ti o da, ni ṣiṣe buburu niwaju Oluwa, ni rirìn li ọ̀na Jeroboamu ati ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀ ti o da, lati mu ki Israeli ki o ṣẹ̀.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:10-23