Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọdun kẹtadilọgbọn Asa, ọba Juda, ni Simri jọba ijọ meje ni Tirsa. Awọn enia si do tì Gibbetoni, ti awọn ara Filistia.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:9-20