Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 16:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ Baaṣa, ati Ela, ọmọ rẹ̀, nipa eyiti nwọn ṣẹ̀, ati nipa eyiti nwọn mu Israeli ṣẹ̀, ni fifi ohun-asán wọn wọnnì mu ki Oluwa, Ọlọrun Israeli binu.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:5-23