Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 15:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nitori Dafidi li Oluwa Ọlọrun rẹ̀ fun u ni imọlẹ kan ni Jerusalemu, lati gbé ọmọ rẹ̀ ró lẹhin rẹ̀, ati lati fi idi Jerusalemu mulẹ:

1. A. Ọba 15

1. A. Ọba 15:1-6