Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 15:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iyokù gbogbo iṣe Asa, ati gbogbo agbara rẹ̀ ati gbogbo ohun ti o ṣe, ati ilu wọnnì ti o kọ́, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Juda? Ṣugbọn li akoko ogbó rẹ̀, àrun ṣe e li ẹsẹ rẹ̀.

1. A. Ọba 15

1. A. Ọba 15:15-29