Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 15:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọdun mọkanlelogoji li o jọba ni Jerusalemu, orukọ iya nla rẹ̀ si ni Maaka, ọmọbinrin Abiṣalomu.

1. A. Ọba 15

1. A. Ọba 15:8-18