Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 14:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun Ahijah, pe, Kiyesi i, aya Jeroboamu mbọ̀ wá bère ohun kan lọwọ rẹ niti ọmọ rẹ̀: nitori ti o ṣàisan: bayi bayi ni ki iwọ ki o wi fun u: yio si ṣe, nigbati o ba wọle, yio ṣe ara rẹ̀ bi ẹlomiran.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:1-12