Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 14:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó iṣura ile Oluwa lọ, ati iṣura ile ọba; ani gbogbo rẹ̀ li o kó lọ: o si kó gbogbo asà wura ti Solomoni ti ṣe lọ.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:24-31