Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 14:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti nhùwa panṣaga mbẹ ni ilẹ na: nwọn si ṣe gẹgẹ bi gbogbo ohun irira awọn orilẹ-ède ti Oluwa lé jade kuro niwaju awọn ọmọ Israeli.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:18-31