Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 14:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jeroboamu si wi fun aya rẹ̀ pe, Dide, emi bẹ̀ ọ, si pa ara rẹ dà, ki a má ba le mọ̀ ọ li aya Jeroboamu; ki o si lọ si Ṣilo: kiyesi i, nibẹ li Ahijah, woli wà, ti o sọ fun mi pe, emi o jọba lori enia yi.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:1-7