Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si lọ, o si ri, a gbé okú rẹ̀ sọ si oju ọ̀na, ati kẹtẹkẹtẹ, ati kiniun duro ti okú na, kiniun kò jẹ okú na, bẹ̃ni kò fà kẹtẹkẹtẹ na ya.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:24-34