Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati woli ti o mu u lati ọ̀na pada bọ̀ gbọ́, o wipe, Enia Ọlọrun na ni, ti o ṣọ̀tẹ si Oluwa: nitorina li Oluwa fi i le kiniun lọwọ, ti o si fà a ya, ti o si pa a, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa, ti o ti sọ fun u.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:17-34