Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si lọ tan, kiniun kan pade rẹ̀ li ọ̀na, o si pa a: a si gbe okú rẹ̀ sọ si oju ọ̀na, kẹtẹkẹtẹ si duro tì i, kiniun pẹlu duro tì okú na.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:19-33