Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SI kiyesi i, enia Ọlọrun kan lati Juda wá si Beteli nipa ọ̀rọ Oluwa: Jeroboamu duro lẹba pẹpẹ lati fi turari jona.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:1-11