Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jeroboamu si dá àse silẹ li oṣu kẹjọ, li ọjọ Kẹdogun oṣu, gẹgẹ bi àse ti o wà ni Juda, o si gun ori pẹpẹ na lọ: bẹ̃ni o si ṣe ni Beteli, o rubọ si awọn ọmọ-malu ti o ṣe: o si fi awọn alufa ibi giga wọnni ti o ti ṣe si Beteli.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:30-33