Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si gbìmọ, o si ya ẹgbọ̀rọ malu wura meji, o si wi fun wọn pe, O pọ̀ju fun nyin lati mã goke lọ si Jerusalemu: Israeli, wò awọn ọlọrun rẹ, ti o mu ọ lati ilẹ Egipti wá!

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:21-30