Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Jeroboamu, ọmọ Nebati, ti o wà ni Egipti sibẹ gbọ́, nitori ti o ti sá kuro niwaju Solomoni ọba, Jeroboamu si joko ni Egipti.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:1-12