Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Solomoni kọ́ ibi giga kan fun Kemoṣi, irira Moabu, lori oke ti mbẹ niwaju Jerusalemu, ati fun Moleki, irira awọn ọmọ Ammoni.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:2-11