Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Solomoni wá ọ̀na lati pa Jeroboamu. Jeroboamu si dide, o si sá lọ si Egipti si ọdọ Ṣiṣaki ọba Egipti, o si wà ni Egipti titi ikú Solomoni.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:34-43