Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Solomoni di arugbo, awọn obinrin rẹ̀ yi i li ọkàn pada si ọlọrun miran: ọkàn rẹ̀ kò si ṣe dede pẹlu Oluwa Ọlọrun rẹ̀, gẹgẹ bi ọkàn Dafidi, baba rẹ̀.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:1-7