Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ẹya kan fun ọmọ rẹ̀, ki Dafidi iranṣẹ mi ki o le ni imọlẹ niwaju mi nigbagbogbo, ni Jerusalemu, ilu ti mo ti yàn fun ara mi lati fi orukọ mi sibẹ.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:35-38