Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun Jeroboamu pe, Iwọ mu ẹya mẹwa: nitori bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi pe, Wò o, emi o fa ijọba na ya kuro li ọwọ Solomoni, emi o si fi ẹya mẹwa fun ọ.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:22-33