Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Jeroboamu, ọmọ Nebati, ara Efrati ti Sereda, iranṣẹ Solomoni, orukọ iya ẹniti ijẹ Serua, obinrin opó kan, on pẹlu gbe ọwọ soke si ọba.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:25-31