Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Hadadi si gbọ́ ni Egipti pe, Dafidi sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, ati pe Joabu olori-ogun si kú, Hadadi si wi fun Farao pe, rán mi lọ, ki emi ki o le lọ si ilu mi.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:14-28