Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn orilẹ-ède ti Oluwa wi fun awọn ọmọ-Israeli pe, Ẹnyin kò gbọdọ wọle tọ̀ wọn, bẹ̃ni awọn kò gbọdọ wọle tọ̀ nyin: nitõtọ nwọn o yi nyin li ọkàn pada si oriṣa wọn: Solomoni fà mọ awọn wọnyi ni ifẹ.

1. A. Ọba 11

1. A. Ọba 11:1-7