Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Alabukún fun li Oluwa Ọlọrun rẹ, ti o ni inu-didùn si ọ lati gbe ọ ka ori itẹ́ Israeli: nitoriti Oluwa fẹràn Israeli titi lai, nitorina li o ṣe fi ọ jọba, lati ṣe idajọ ati otitọ.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:7-17