Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 10:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kẹkẹ́ kan ngoke o si njade lati Egipti wá fun ẹgbẹta ṣekeli fadakà, ati ẹṣin kan fun ãdọjọ: bẹ̃ni nwọn si nmu wá pẹlu nipa ọwọ wọn fun gbogbo awọn ọba awọn ọmọ Hiti ati fun awọn ọba Siria.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:24-29