Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 10:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu awọn ọ̀wọ-ọkọ̀ Hiramu ti o mu wura lati Ofiri wá, mu igi Algumu, (igi Sandali) lọpọlọpọ ati okuta oniyebiye lati Ofiri wá.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:7-16