Yorùbá Bibeli

Esr 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Ṣeṣbassari na wá, o si fi ipilẹ ile Ọlọrun ti o wà ni Jerusalemu lelẹ: ati lati igba na ani titi di isisiyi li o ti mbẹ, ni kikọ kò si ti ipari tan.

Esr 5

Esr 5:7-17