Yorùbá Bibeli

Esr 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin na nwọn si ru ẹbọ sisun igbagbogbo ati ti oṣu titun, ati ti gbogbo ajọ Oluwa, ti a si yà si mimọ́, ati ti olukuluku ti o fi tinu-tinu ru ẹbọ atinuwa si Oluwa.

Esr 3

Esr 3:1-12