Yorùbá Bibeli

Esr 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esra si dide, o si mu awọn olori ninu awọn alufa, awọn ọmọ Lefi, ati gbogbo Israeli bura pe, awọn o ṣe gẹgẹ bi ọ̀rọ wọnyi. Nwọn si bura.

Esr 10

Esr 10:1-7