Yorùbá Bibeli

Esr 10:39-44 Yorùbá Bibeli (YCE)

39. Ati Ṣelemiah, ati Natani, ati Adaiah,

40. Maknadebai, Saṣai, Ṣarai,

41. Asareeli, ati Ṣelemiah, Ṣemariah.

42. Ṣallumu, Amariah, ati Josefu.

43. Ninu awọn ọmọ Nebo; Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Ṣebina, Jadau, ati Joeli, Benaiah.

44. Gbogbo awọn yi li o mu ajeji obinrin ba wọn gbe, omiran ninu wọn si ni obinrin nipa ẹniti nwọn li ọmọ.