Yorùbá Bibeli

Esr 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ohun-èlo wura ati ti fadaka jẹ ẹgbẹtadilọgbọn. Gbogbo wọnyi ni Ṣeṣbassari mu goke wá pẹlu awọn igbekun ti a mu goke lati Babiloni wá si Jerusalemu.

Esr 1

Esr 1:6-11