Yorùbá Bibeli

Eks 7:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Farao ki yio gbọ́ ti nyin, emi o si fi ọwọ́ mi lé Egipti, emi o si fi idajọ nla mú awọn ogun mi, ani awọn ọmọ Israeli enia mi, jade kuro ni ilẹ Egipti.

Eks 7

Eks 7:3-5